الْمَقَامَةُ الرَّحْبِيَّةُ
Contents
Chapter 10

الْمَقَامَةُ الرَّحْبِيَّةُ

Share
No verses match your search
101

حَتَّى إِذَا أَعْفَى بَعْدَ إِسْفَارِ الصُّبْحِ.


English

Until he is pardoned after the dawn breaks.

Yoruba

Títí tí a ó fi dárí jì í lẹ́yìn tí ìlà-oòrùn bá yọ.

102

بِمَا بَقِيَ مِنْ مَالِ الصُّلْحِ.


English

With what remains of the reconciliation money.

Yoruba

Pẹ̀lú ohun tí ó kù nínú owó ìlàjà.

103

تَخَلَّصَتْ قَائِبَةٌ مِنْ قُوبٍ.


English

A chick is freed from its shell

Yoruba

Oromọdiẹ lè bọ sílẹ̀ kúrò nínú èpò rẹ .

104

وَبَرِئَ بَرَاءَةَ الذِّئْبِ مِنْ دَمِ ابْنِ يَعْقُوبَ.


English

And be as innocent as the wolf from the blood of Jacob's son.

Yoruba

Kí ó sì jẹ́ aláìlẹ́ṣẹ̀ bí ìkookò ṣe bọ kúrò nínú ẹ̀jẹ̀ ọmọ Jákọ́bù.

105

فَقَالَ لَهُ الْوَالِي: مَا أُرَاكَ سمْتَ شَطَطًا.


English

The governor said to him: I don't see you demanding excess.

Yoruba

Gómìnà náà sọ fún un pé: Èmi kò rí i pé o ń béèrè fún àṣejù.

106

وَلَا رمْتَ فَرَطًا.


English

Nor have you sought extremism.

Yoruba

Bẹ́ẹ̀ ni o kò wu ìwà àṣejù.

107

قَالَ الْحَارِثُ بْنُ هَمَّامٍ:


English

Al-Harith bin Hammam said:

Yoruba

Hárìsù ọmọ Hammam sọ pé:

108

فَلَمَّا رَأَيْتُ حُجَجَ الشَّيْخِ كَالْحُجَجِ السُّرَيْجِيَّةِ.


English

When I saw the old man's arguments like those of son of Saruj

Yoruba

Nígbà tí mo rí àwọn ẹri àgbàlagbà náà bí ti ọmọ Saruji,

109

عَلِمْتُ أَنَّهُ عَلَمُ السَّرُوجِيَّةِ.


English

I knew he was the Glory of the Sarujites.

Yoruba

Mo mọ̀ pé òun ni ògo àwọn ará Saruj.

110

فَلَبِثْتُ إِلَى أَنْ زَهَرَتْ نُجُومُ الظَّلَامِ.


English

So I waited until the stars of darkness bloomed.

Yoruba

Nítorí náà mo dúró títí tí àwọn ìràwọ̀ òkùnkùn fi tàn.

© , Qatru