With a heart like the wolf’s, and resolve I act.
Pẹ̀lú ọkàn bíi ti ikòko, mo ṣe pẹ̀lú ìpinnu.
At times I lack, at times I am rich, yet
Nígbà míì mo dá bí áláìní, nígbà míì mo ní ọlá, ṣùgbọ́n
Wealth is attained by the distant, humble one.
ẹni tó jìnnà sí ilé tí o sí n ṣe ìgbìyànjú, yóò rí ọla.
No anxiety from poverty, that exposes,
Kò sí ìbànújẹ àtúní làṣìrí nínú ìyà,
Nor boasting beneath wealth that I could imagine.
Kò sí ìgbéraga lábẹ́ ọlá tí mo lè rò.
The ignorants can not over look my forbearance, nor am I seen
Àwọn òmùgọ̀ kò lè yẹ̀pẹ́rẹ́ ìfarada mi, wọn kò sì ni rí mi
As one who begs at the tails of words, fumbling.
Bí ẹni tí ń bẹ̀bẹ̀ fún ọ̀rọ̀ ẹ̀yìn, tí ń ṣe ofofo
And on a night of misfortune, its master kindles the bow.
Melo melo lòru òtútù, tí olùní ọfà ń dáná sun ọ́fà.
And the arrows which he do shoot with.
O sì tún gé àwọn igi ọfà tí ó fi ń tafà.
I trampled upon a rainy darkness of a night, and my companions are
Mo wọ̀nu òkùnkùn òrú tí ń rọ̀ òjo, àwọn ọ̀rẹ́ mi nínú orú yìí sì jẹ́