Were hunger, snows, fear, and thunders
Wọ́n jẹ́ èébì, òkúta yìnyín, ìbẹrù, àti arà
I widowed women and orphaned children.
Mo sọ àwọn obìnrin di opó, mo sì sọ́ àwọn ọmọ di òrùkàn
And I returned as I began, while the night grew darker.
Mo padà bí mo ṣe bẹ̀rẹ̀, nígbà tí òkùnkùn òrú n dúdú gidigidi
And at Ghumaysa, two groups sat about me.
Ní Ghumaysa, ẹgbẹ́ méjì jókòó nípa mi.
Two parties: one questioned, the other asking.
Ẹgbẹ́ méjì: ọ̀kan ń dáhùn, ìkejì ń béèrè.
They said: our dogs barked in the night.
Wọ́n ní: àwọn ajá wa ké ní òru.
We said: was it a wolf prowling, or an hyena wandering?
A ní: ṣé ikòko ló ń rìn, tàbí ajagbó ló ń kọ̀ já?
It was but a faint sound, then it subsided.
Kò jẹ́ bí kò ṣe ìró kékeré, lẹ́yìn náà ó dákẹ́.
We said: was it a sand-grouse startled, or a falcon disturbed?
A ní: ṣé ẹyẹ Tatanbara ní wọn dẹ̀rùbà ní, tàbí àṣá?
If it be of jinn, its late night movement is damn creepy!.
Tí ó bá jẹ́ ti alujanú ní, kí kọ já rẹ lóru yìí kayefi ní!.